mbolaji2 (OP)
Newbie
Offline
Activity: 74
Merit: 0
|
|
November 04, 2017, 03:44:03 PM |
|
Asiko ni fun away omo Yoruba lati ma so ede tiwa naa ni ibi gbogbo, ki ole ran ede wa lowo, papajulo ni gbogbo agbaye
|
|
|
|
whalez
Member
Offline
Activity: 140
Merit: 10
|
|
November 12, 2017, 03:33:18 PM |
|
Inu mi dun lati je omo ibile yoruba... Awa la ni asa awa naa lani owe... Awa Yoruba lani arikose rere lara. Eja ka fowo sowopo ka gbe asa wa laruge!...
|
|
|
|
bitcoineers
Jr. Member
Offline
Activity: 40
Merit: 1
FREE Cryptocurrency Decentralized Exchange
|
|
October 12, 2018, 10:32:57 AM |
|
E kaa ro sori eto awarawa omobibi kaaro o ojiire. Ejé ka jumô gbé isé yorùbá wa lárugê. Ê seun. Samuel
|
Tokenmom - FREE Cryptocurrency Decentralized Exchange Get 1000 FREE TM COINS at Tokenmom.com (https://www.Tokenmom.com/)
|
|
|
mbolaji2 (OP)
Newbie
Offline
Activity: 74
Merit: 0
|
|
October 28, 2019, 01:02:17 AM |
|
Ede wa asa wa koni baje ooo
|
|
|
|
MadEth
Jr. Member
Offline
Activity: 140
Merit: 2
|
|
December 09, 2019, 02:19:26 PM Merited by d5000 (1), posi (1) |
|
Nla lati wo intiative ti o jẹ ede abinibi ti orilẹ-ede Naijiria, Lọwọlọwọ ede Yoruba ni gbogbo agbaye sọ nitorinaa o yẹ ki o jẹ idanimọ, Mo nireti paṣipaarọ crypto laipe bi Huobi Global https://www.huobi.br.com/topic/invited/?invite_code=u8s64 yoo ni itumọ Yorùbá ti ipilẹ Syeed rẹ.
|
|
|
|
abdulfatah.busari
Jr. Member
Offline
Activity: 462
Merit: 1
|
|
February 16, 2020, 09:33:30 PM |
|
Ekú deédé asìkò yi o. Èmi jé IMO Bibi ipinle Òsun. Inú mi dun lato darapò mónyín níbí.
|
JACS ♦♦♦ Internet 3.0 Decentralized Infrastructure ▬▬▬▬▬▬ https://www.jacs.tech/ ▬▬▬▬▬▬
|
|
|
Official james
Jr. Member
Offline
Activity: 70
Merit: 5
|
|
April 06, 2020, 07:13:08 PM |
|
Eku dede asikoyi, Ara o le bi ? A de ku gbogbo rogbodiyan to shele ni agbalaye, ajalu buruku ko ni je ti gbogbo wa lola eledumare, eje ka tu bo tesiwaju nipa bi ase ma gbe asha wa laruge
|
|
|
|
Keltrentt
Jr. Member
Offline
Activity: 108
Merit: 1
|
|
May 16, 2020, 06:54:12 PM |
|
Waawu! O ya mi l'enu l'opo l'opo lati ri wipe ede Yoruba ni aaye oto l'ori website yi. Inu mi si dun sii gidi gidi ni. Nje a ri eni ti o le fun mi ni merit? Inu mi yio dun gidi gaan ni. Ese pupo pupo...
|
|
|
|
Mpamaegbu
Legendary
Offline
Activity: 2842
Merit: 1226
Once a man, twice a child!
|
|
May 25, 2020, 05:00:06 AM |
|
Waawu! O ya mi l'enu l'opo l'opo lati ri wipe ede Yoruba ni aaye oto l'ori website yi. Inu mi si dun sii gidi gidi ni. Nje a ri eni ti o le fun mi ni merit? Inu mi yio dun gidi gaan ni. Ese pupo pupo...
Kilo je "Waawu" nibiye? Shey nyi je ijile ede Yoruba ni? Mo ro kpe ede English niye.
|
Before you boast of your material acquisition, take a stroll to a morgue and there you will find those who were once better than you're. Only fools think they've it all. Stay humble 🤔
[/color]
|
|
|
abdulfatah.busari
Jr. Member
Offline
Activity: 462
Merit: 1
|
|
June 01, 2020, 02:54:36 PM |
|
Waawu! O ya mi l'enu l'opo l'opo lati ri wipe ede Yoruba ni aaye oto l'ori website yi. Inu mi si dun sii gidi gidi ni. Nje a ri eni ti o le fun mi ni merit? Inu mi yio dun gidi gaan ni. Ese pupo pupo...
Kilo je "Waawu" nibiye? Shey nyi je ijile ede Yoruba ni? Mo ro kpe ede English niye. Modúpé gidigidi fún meriti tí e fi dá mi Lola o. Mon lóore o
|
JACS ♦♦♦ Internet 3.0 Decentralized Infrastructure ▬▬▬▬▬▬ https://www.jacs.tech/ ▬▬▬▬▬▬
|
|
|
abdulfatah.busari
Jr. Member
Offline
Activity: 462
Merit: 1
|
|
June 01, 2020, 02:57:56 PM |
|
O wumi lati mọn nípa bi a sele tèsíwájú láti lè máa pa owó pẹlu kiriptokurensi. Inú mi yíò dun láti mọn awọn ọna daada na. Gbogbo wa lao se orire o. Amin
|
JACS ♦♦♦ Internet 3.0 Decentralized Infrastructure ▬▬▬▬▬▬ https://www.jacs.tech/ ▬▬▬▬▬▬
|
|
|
Keltrentt
Jr. Member
Offline
Activity: 108
Merit: 1
|
|
June 18, 2020, 01:20:16 AM |
|
Waawu! O ya mi l'enu l'opo l'opo lati ri wipe ede Yoruba ni aaye oto l'ori website yi. Inu mi si dun sii gidi gidi ni. Nje a ri eni ti o le fun mi ni merit? Inu mi yio dun gidi gaan ni. Ese pupo pupo...
Kilo je "Waawu" nibiye? Shey nyi je ijile ede Yoruba ni? Mo ro kpe ede English niye. Otito ni oro ti e so...ede ayalo ni a le kaasi. Sugbon ju gbogbo re lo, mo dupe gidigidi l'owo yin fun bi e ti se fun mi ni merit ti mo beere fun. ko ni tan lowo yin o! Amin! Eseun leekan si
|
|
|
|
smilex12
Newbie
Offline
Activity: 12
Merit: 3
|
|
July 06, 2020, 02:04:44 PM |
|
eyi jẹ ede lati ṣe agberaga fun. ṣugbọn bawo ni awa ọmọ Nigeria ti n ṣe igbega aaye aye crypto ni orilẹ-ede wa?
|
|
|
|
Alobo Realer
Member
Offline
Activity: 127
Merit: 12
|
|
July 12, 2020, 10:19:15 PM |
|
Ede wa n dagba laisi idaduro, ati pe yoo ma tẹsiwaju lati dagbasoke. ni awọn ọdun diẹ ti mbọ to o yoo mọ ni agbaye ati pe yoo kọ ọ ni diẹ ninu awọn aye miiran ti agbaye
|
|
|
|
abdulodoi
Member
Offline
Activity: 91
Merit: 35
|
|
August 12, 2020, 07:03:36 PM |
|
Eku irole eyin omo oduduwa, inu mi dun lati rii wipe ede abininibi se patiki fun wa lopolopo. Olorun a tun bo ma gbe wa ga ninu gbogbo ohun ti a ba dawo le o. A ni so owo nu, ori buruku o ni je tiwa o. Amin.
Se enikeni mo ti aba ni ile ise crypto to gbajumo ni naijiria?
|
|
|
|
abdulfatah.busari
Jr. Member
Offline
Activity: 462
Merit: 1
|
|
August 18, 2020, 10:41:48 PM |
|
Ẹ un' le nibi o
|
JACS ♦♦♦ Internet 3.0 Decentralized Infrastructure ▬▬▬▬▬▬ https://www.jacs.tech/ ▬▬▬▬▬▬
|
|
|
laycon
Member
Offline
Activity: 154
Merit: 10
|
|
September 26, 2020, 04:00:16 PM |
|
Inu mi dun lopo lopo wipe anfani wa fun wa lati so ede abi nibi wa ton se Yoruba. Aba kon soso ti moni ni wipe awon ara wa ti won ba ti wa loke ninu forumu Yi ni lati ran awa ti aba sese bere(newbie) lati de oke ninu forumu Yi. Aba mi o ju yelo
|
|
|
|
Charles-Tim
Legendary
Offline
Activity: 1694
Merit: 5166
Leading Crypto Sports Betting & Casino Platform
|
|
May 10, 2021, 07:04:43 AM Last edit: May 10, 2021, 10:26:50 AM by Charles-Tim |
|
Inu mi dun lopo lopo wipe anfani wa fun wa lati so ede abi nibi wa ton se Yoruba. Aba kon soso ti moni ni wipe awon ara wa ti won ba ti wa loke ninu forumu Yi ni lati ran awa ti aba sese bere(newbie) lati de oke ninu forumu Yi. Aba mi o ju yelo
Otito ni wipe ede Yoruba o dara lopo lopo, sugbo a ni opo lopo lati se lati te si iwaji. A ni lati mo nipa bitcoin ati altcoin, ki awa lara awon ti o ma posti ni board gbogbogbo, nipa eyi, a ma te siwaju. O ma dara ki a wa si ibi lati ni ajoro ati lati beere ohun ti a ba mo nipa bi a se le lo bitcoin ati altcoin.
|
..Stake.com.. | | | ▄████████████████████████████████████▄ ██ ▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄ ▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄ ██ ▄████▄ ██ ▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀ ██████████ ▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀ ██ ██████ ██ ██████████ ██ ██ ██████████ ██ ▀██▀ ██ ██ ██ ██████ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██████ ██ █████ ███ ██████ ██ ████▄ ██ ██ █████ ███ ████ ████ █████ ███ ████████ ██ ████ ████ ██████████ ████ ████ ████▀ ██ ██████████ ▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄ ██████████ ██ ██ ▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀ ██ ▀█████████▀ ▄████████████▄ ▀█████████▀ ▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄███ ██ ██ ███▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄ ██████████████████████████████████████████ | | | | | | ▄▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▄ █ ▄▀▄ █▀▀█▀▄▄ █ █▀█ █ ▐ ▐▌ █ ▄██▄ █ ▌ █ █ ▄██████▄ █ ▌ ▐▌ █ ██████████ █ ▐ █ █ ▐██████████▌ █ ▐ ▐▌ █ ▀▀██████▀▀ █ ▌ █ █ ▄▄▄██▄▄▄ █ ▌▐▌ █ █▐ █ █ █▐▐▌ █ █▐█ ▀▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▀█ | | | | | | ▄▄█████████▄▄ ▄██▀▀▀▀█████▀▀▀▀██▄ ▄█▀ ▐█▌ ▀█▄ ██ ▐█▌ ██ ████▄ ▄█████▄ ▄████ ████████▄███████████▄████████ ███▀ █████████████ ▀███ ██ ███████████ ██ ▀█▄ █████████ ▄█▀ ▀█▄ ▄██▀▀▀▀▀▀▀██▄ ▄▄▄█▀ ▀███████ ███████▀ ▀█████▄ ▄█████▀ ▀▀▀███▄▄▄███▀▀▀ | | | ..PLAY NOW.. |
|
|
|
Issa56
|
|
August 08, 2021, 06:02:15 PM |
|
Oye ka le ma reran wa lowo pelu merit nibi. Lati ma ran our omo yoruba lowo lati ma sha awon ishe signature.
|
| Duelbits | ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ | | TRY OUR UNIQUE GAMES! ◥ DICE ◥ MINES ◥ PLINKO ◥ DUEL POKER ◥ DICE DUELS | | | | █▀▀ █ █ █ █ █ █ █ █ █ █ █ █▄▄ | ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ | ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ | ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ | ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ | ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ ███ ▀▀▀ | | ▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀▀ KENONEW ▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄▄ | ▀▀█ █ █ █ █ █ █ █ █ █ █ █ ▄▄█ | | 10,000x MULTIPLIER | | ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ | | ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ ██ |
[/tabl
|
|
|
adeyemirichard71
Newbie
Offline
Activity: 25
Merit: 1
|
|
September 07, 2021, 07:15:25 PM |
|
Ekale ooooh Eyin temi bawo ni, inumidun pe MO wa nibi. Ede yoruba ATI Asa yoruba MA gbe wa ooo Ayewada koni baje fun wa
|
|
|
|
|