Nathrixxx
|
|
September 08, 2021, 05:18:35 PM |
|
Mo ki gbogbo ile oooooo omoluabi a gbe wa ooooooooo oruko temi ni Nathrixxx ni forum apejopo was yi, inu mi dun pupo lati was laarin awon omo iya mi tooto, omo ilu Oyo ni ogbomoso ajilete ni bi ti nwan tin mu eko yangan Lori Amala to gbona felifeli, oruko ile baami ni ile abgoro ni eyin okeleerin adugbo aaje.
|
|
|
|
Davidvictorson
|
|
September 17, 2021, 04:00:06 PM |
|
Mo ki gbogbo ile oooooo omoluabi a gbe wa ooooooooo oruko temi ni Nathrixxx ni forum apejopo was yi, inu mi dun pupo lati was laarin awon omo iya mi tooto, omo ilu Oyo ni ogbomoso ajilete ni bi ti nwan tin mu eko yangan Lori Amala to gbona felifeli, oruko ile baami ni ile abgoro ni eyin okeleerin adugbo aaje.
I'm not Yoruba but two of the most important words which I heard most frequently during my brief stay in Kwara State, Oyo State and Ogun State and even among Yorubas in non-yoruba speaking states are: 1- eloni (how much?) 2- Soro Soke (speak up) - This one has an emotional undertone for me. We know why already.
|
|
|
|
Mpamaegbu
Legendary
Offline
Activity: 2870
Merit: 1233
Once a man, twice a child!
|
|
September 22, 2021, 02:00:44 AM |
|
I'm not Yoruba but two of the most important words which I heard most frequently during my brief stay in Kwara State, Oyo State and Ogun State and even among Yorubas in non-yoruba speaking states are:
1- eloni (how much?) 2- Soro Soke (speak up) - This one has an emotional undertone for me. We know why already.
And you didn't hear all the "Eku igbadu"? and "Eku Alejo"? That means you didn't flex while you were there then 😅
|
|
|
|
Seaking009
Newbie
Offline
Activity: 9
Merit: 0
|
|
November 09, 2021, 09:21:20 AM |
|
Eyin temi bawo ni, adeku Orilede wa yin olorun ama bá denku orisirisi to selé ninu dié toku kì odun Eyin pari edumare awa pelu wa tebi tara.
|
|
|
|
Spacebar96
Newbie
Offline
Activity: 131
Merit: 0
|
|
March 08, 2022, 08:14:54 PM |
|
Moki gbogbo omo yoruba towa ni forum yi Pata Pata, inu mi dun lati se awari forum ede yoruba. Pataki forum yini bi ati lese afani fun arawa gege bi omo yoruba. Ti eba wo awujo wa ni oni eripe owun orisi risi nkan losenle, ti eba wo country wa eri wipe ko si opportunities fun awa odo tori re lofiye ki aran arawa lowo. Bi abari update to le se afani fun awujo wa ki ama hesitate lati je ki awon egbe wa ma ni pare. Olorun ama tewa siwaju.
|
|
|
|
Bamjos
Member
Offline
Activity: 71
Merit: 22
|
|
May 01, 2022, 03:52:58 PM |
|
Akú àkókò yí ooo! Inú mi dun láti rí wípé àyè wáà fún àwa omo yorùbá láti so èdè abínibí wa lóri forùmù yìí, ìdùnú ńlá lójé fúmi, mosì lérò pé aó fi ànfàní yìí dóòré pèlú ara wa, àti láti ran ra wa lówó lóri forùmù yí.
Osù méta séyìn ni mo darapò mó fórùmù yí, nkan ò rorùn ní ìbèrè, sùgbón mo dúpé lówó olóun pé mo ń tèsíwájú; mosì setán láti ní òré àti láti kó nípa bí ènìyàn selè se àseyorí lóri forùmù.
|
|
|
|
Makacrypto
Newbie
Offline
Activity: 44
Merit: 0
|
|
August 05, 2022, 08:20:50 AM |
|
Inu mi dun lati darapo mo ipejopo yi, mode fe je ki gbogbo wa fowosopo lati ranrawa lowo,
|
|
|
|
emmy.princet
Newbie
Offline
Activity: 195
Merit: 0
|
|
August 05, 2022, 07:21:00 PM |
|
Mo ki yin gbo omo oduduwa oooo..., a daara ko gbogbo wa ooo.
|
|
|
|
Cryptomultiplier
|
|
August 06, 2022, 03:21:50 PM |
|
I do not speak yoruba language but I had to learn some for easy community relations. Some of the word commonly used are; • eloni - how many •wa jewun - come and eat •meji -2 •meta - 4 •ekaro - good morning •eka sun - good afternoon •odaro - goodnight
So many to say but these came out quickly.
|
████████████████████ OrangeFren.com ████████████████████instant KYC-free exchange comparison████████████████████ Clearnet and onion available #kycfree + (prepaid Visa & Mastercard) ████████████████████
|
|
|
Makacrypto
Newbie
Offline
Activity: 44
Merit: 0
|
|
August 07, 2022, 07:23:32 PM |
|
Ede to dungbo leti ni ede yoruba to dun so lawujo, if anybody have interest in learning it I'm available to help them. Cause I'm happy how my language is been speaking here.
|
|
|
|
Merit.s
|
|
December 20, 2022, 11:43:38 PM |
|
Ekale ni bi o,awon omo iya mi Mi o mo pe ani ibi bayi ni ile yi Baba Nla Mmpamegbu elenu pa bi ese da ibi ti ati le soro ni ede Yoruba. Olorun lo ma gbo adura wa Koni baje.
|
|
|
|
Cecilia Joytwin
Newbie
Offline
Activity: 17
Merit: 0
|
|
January 01, 2023, 09:10:08 PM |
|
E kaale nibi o Se awa omo Yorùbá sii wa nibi abi atilo?
|
|
|
|
Mamapami
Newbie
Offline
Activity: 15
Merit: 0
|
|
March 02, 2024, 11:07:29 PM |
|
Inu mi lati wa larin yin nibi.
|
|
|
|
Mamapami
Newbie
Offline
Activity: 15
Merit: 0
|
|
March 12, 2024, 08:40:03 PM |
|
Nje gbogbo wa le ran arawa lowo lati ma fun ra wa ni merit daradara. Ati wipe sale se afihan ibi to gbogbo wa tiwa, tori wipe kale mo opportunity ta lagbara latise fun rawa.
|
|
|
|
|